Wednesday, October 27, 2021

O Dara Ki Oje Wewe Onkowe Se Ise Pataki To Se Fihan Ni Awujo - Ayinde Omogbolahan Abiodun

 

O DARA KI OJE WEWE ONKOWE SE ISE PATAKI TO SE FIHAN NI AWUJO - AYINDE OMOGBOLAHAN ABIODUN

 



Ayinde Omogbolahan Abiodun  je okan lara omo Egbe Ede Ati Asa Loyin La Dun Ile Yoruba. Ninu iforowero pelu Wole Adedoyin, o so nipa iriri re gege bi Oje Wewe Onkowe ati awon iwe ti o ti ko.

 

WA:  BAWO LOSE BERE? KÍNNI OTI KO ATI WIPE KIN LÓ N KO LOWO?

AYINDE:  Mo bere itan kiko ni ede Yoruba lati bi odun melo si eyin Lori ikanni Facebook beni moti ko awon bi itan ololajulo anjofe ati itan eranko Ekun ati olode lowo lowo bai mo nko itan aroso kan lowo ninu ipele face book ninu grupu basotan ile Yoruba ati iriri aiye itan meji lo nlowo bai akoko ogboju ode ninu Igbo aginju iberu  itan ikeji ilu awon oku.

 

WA: KÍNNI IKAN TO WU E LORI TI O FI RO PÉ IWO NAA FE MÁA KO NKAN

AYINDE:  Ikan towumi Lori nipe ati kekere Mi ni ASA ati Ede Yoruba tiwo mu pupo beni awon itan alagbara tiwon tijaa fun ile Yoruba timo tigbo tunje ikan iwuri Funmi

 

WA: TANI OUN WO GEGE BI AWO KOSE, ATI WIPE KÍNNI IDI TI ENI NAA FI JE AWOKOSE FÚN E.

AYINDE:  Eni akoko timowo kose ni Olodumare asiwaju aiye ati orun pelu awon mere mere todasi aiye Eni ikeji toje ki itan kiko tunwu Mi ologbo baba wa fagun wa pelu biwon sefi ede Yoruba da ara iree loni ran nran

 

WA:  AMORAN WO LO LE GBA AWON OJE WEWE TO SESE BO.

AYINDE:  Imoran akoko nipe iwa igberaga igbera sanle kayo kuro ninu Oro wa beni ki odo se Ise Pataki tose fihan ni awujo aforiti suru na tunkun imoran mi pelu ibowo fun agbalagba

 

WA: KÍNNI AWON NKAN TI MÁA N TIE KO NKAN TI N KO YEN.

AYINDE:  Nkan rere Yewa ni ile Yoruba beni Pataki niki awon Ijobawa pelu awon Oba alaye se atileyin fun ede Yoruba koma ba paa run

 

WA:  SE O NI ILANA TO FI KO NKAN TO N KO,ABI ONI ONA KAN PATO TO N KO NKAN LE LORI?

AYINDE:  Beni moni ilana topo Dada timoko itan Mi le Lori akoko ede Yoruba Mi o fe koparun beni ni imura Iwo aso iwu wasi awa eniyan pelu ojuse omoluabi larin awon eniyan pelu Oro ogbon ati oye to nso pupo ninu Oro aiye Omo eniyan

 

WA:  BAWO LESE BERE? IGBA WO LO BERE? KÍNNI IDI TOFI BERE?

AYINDE:  Ati kekere nimoti je eniyan toferan atima kaa iwe ni ede Yoruba beni atigbana lotiwu emi na wipe ti olodumare bafunmi ni afaani mafi opolo Mi GBE ASA ati Ede Yoruba laruge jakejado agbalaye itan Mi koni odun kan bai ni pato tori ati kekere nimoti ma hun ogbon ati inu daa lati ko itan  ama awon eniyan mawa pelu itan kiko bai bi odun mejo si eyin ni

 

WA:  ÌWÉ WO LO KOKO GBÉ JADE

AYINDE:  Olodumare kiti Funmi ni oore ofe atigbe iwe kankan jade ama awon itan Mi timo tiko Lori gurupu Mi ni face book koni onkaa rara itan polo repete ni akoko itan Mi akoko ti aiye fimo mami loni itan ni itan ololajulo anjofe pelu ogboju ode ninu Igbo aginju iberu ati ilu awon oku awon Miran tun poni Ibe timi o le daa oruko tan

 

WA:  SE ONI NKANKAN PATO TÓ MÁA N FI ISE RE SUN

AYINDE:  Beni moni ikan pato akoko ikan pato Mi ni latigbe ola ede Yoruba ati ASA ile Yoruba gun oke agba atipe bi aiye se nloyi agbodo fi itan Yoruba so pupo Oro agba fun awon eniyan

 

WA:  BAWO L'OSE RI NIGBA TÓ N FI AWON NKAN TO N KO S'OWO SITA.

AYINDE:  Inu Mi dun gan ni ayomi kun lasiko timo baju itan sori aiyelujaara ikan ni Facebook ti awon eniyan si nkan saraa Simi

 

WA:  IKAN TO N KO YEN IBO LOTI RI ILANA TO N LO.

AYINDE:  Akoko ilana Mi olodumare ni akoko beni ilana Mi awon baba wa ati Iya wa ni arugbo ni emi sunmo beni awon niwon fi pupo itan aiye won abi ogbon agbaa fitomi si ilana

 

WA: ẸNI TÍ N BO GBÉ ÌWÉ RE JÁDE IBO LETI PADE?

AYINDE:  Akoko Olodumare kiti fi afaani kagbe iwe sita si igboro fun awon eniyan ama olodumare funwa ni afaani atijo sorosoro presenter Lori ikanni Turaka Radio TV network   mopade Eni na nipa aburo Mi kan ti ohun naje olukotan bi temi ni bi odun melo seyin

 

WA:  TOBA JU ISE RE SI IGBORO KINNI AWON ESI TO RI LATI ODO ÀWON TÓ N KA

AYINDE:  Timobaju awon eto mo timo mase itan aroso okunkun ife Lori ikan ni Turaka radio TV network sori Facebook awon eniyan tiwon ba nwo Mi won mose pupo adua Funmi gegebi Omo akin alafori Omo Yoruba Pataki

 

WA: BAWO NI AWON EYAN SELE MO E SÍ?

AYINDE:  Akoko ki awon eniyan ma misi oni iwa irele eniyan to nfi gbogbo Ojo aiye bere imo kun imo Lodo awon agbalagba olukotan ile Yoruba ati agbe ASA ati Ede Yoruba large

 

WA: KÍNNI OGBON TÓ N TASI,TI WU AYÉ LORI TI AYE FI GBA ITAN RE

AYINDE:  Kosi ogbon kan kan nibikan toju Olodumare na lo tori inu aiye latiri ogbon aiye fiko awon eniyan akoko arojinle dara pupo beni ifarabale isunmo agbalagba se Pataki ninu ogbon timo dasi

 

WA: SE IWO NAA MO AWON ASISE KEKEKE TI AWON ONKOWE TO SESE BERE MÁA N SE.

 AYINDE:  Pataki asise ti emi ripe ofaa ti asise fi nde nipe akoko iteriba fun awon agbalagba se Pataki pupo beni iwa mo gbon tan mo matan asima po pupo ninu won Lara won koni gbaa ogbon ologbon se ogbon beni won koni gbaa imoran kun imoran tiwon nikan loma yewon pupo ninu asise temi ri nu gegebi oye temi

 

WA: EWO NINU AWON ITAN RE LO GBÁDÙN NI KIKO JU

AYINDE:  Haa itan timoferan ati makoju ni itan ogboju ode ninu Igbo aginju iberu ati ilu awon oku timo ko lowo lowo bai

 

WA: ÌWÉ TO KOKO GBÉ JADE KÍN LÓ SO NÍPA RE,BAWO NI IRIN AJO GBIGBE IWE NÁÀ JADE SERI

AYINDE:  Akoko Mi o tigbe iwe kankan jade ri Olodumare la nbe kosi ilekun iranlowo re ama moti se eto Lori ikanni Facebook Turaka radio TV network Dada itan ni aroso ni okunkun ife ni akole itan na Ibe latiso pupo ninu isoro wala idamu ti Oko ati Iyawo mofi oju wi ina leyin igbeyawo ori online YouTube Lori Facebook nikan ni awon eniyan tile je afaani eto na

 

WA: KÍNNI AWON ISE TI O N FI IWE NÁÀ RÁN SÍ ÀWÙJO

AYINDE:  Mofi awon itan Mi ranse si awujo wipe ki gbogbo ranti aiye atijo kiwon WO imura aiye atijo pelu imu ra Iwo aso obinrin ati okunrin tofidi ihoho irun un odaa kikun pupa Lori Omo okunrin kodaa irin ihoho Omo wundia ni igboro koda beni mofi itan Mi to awon eniyan si ona ni ilana toye ki Omo Yoruba Pataki toye koto beni mofi itan Mi mu inu awon eniyan dun

 

WA: BAWO L'ASE LERI E LORI AYELUJARA

AYINDE:  Oruko Mi Lori Facebook ni basotan ayinde omogbolan beni elewa gurupu basotan ile Yoruba ati iriri aiye Lori Facebook etunle rimi WO Lori ikan Turaka radio TV network mowa Lori ikan ni WhatsApp 08143632386

No comments:

Post a Comment